Báwo ní ọ ṣe wù ọ láti bèrè?
Kọ́ ìdàgbàsókè Ethereum
Kà nípa àwọn ìmọ̀ràn ìpìlẹ̀ àti àkópọ̀ Ethereum pẹ̀lú àwọn ìwé àṣẹ wa.
Kọ ẹ̀kọ́ nípasẹ̀ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́
Kọ́ ẹ̀kọ́ ìdàgbàsókè Ethereum ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé láti ọ̀dọ̀ àwọn olùpilẹ̀ṣẹ̀ tó ti ṣé tẹ́lẹ̀.
Bẹ̀rẹ̀ ìdánwò
Ṣé o fẹ́ kọ́kọ́ ṣe ìdánwò, béèrè àwọn ìbéèrè nígbà mìíràn?
Ṣètò àyíká agbègbè
Gbáradi àkópọ̀ rẹ fún kíkọ́ nípasẹ̀ àtúntò agbègbè ìdàgbàsókè kan.
Kọ́ gbogbo àwọn ìmọ̀ràn pàtàkì jùlọ nípasẹ̀ kíkọ́ lórí Ethereum
Àlàkalẹ̀ ẹ̀kọ́ lórí Ethereum(opens in a new tab)Nípa àwọn ohun èlò olùgbéejáde
ethereum.org wà níbí láti ràn ọ́ lọ́wọ́ láti kọ̀wé pẹ̀lú Ethereum pẹ̀lú àwọn ìwé ìpamọ́ tó dá lórí àwọn èròǹgbà ìpilẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀lú àkópọ̀ ìdàgbàsókè. Pẹ̀lú pẹ̀lú, àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan wà láti mú ẹ dìde àti ṣiṣẹ́.
Nẹtiwọọki Olùgbéejáde Mozilla ní ọ jẹ ìmísí, a rò pé Ethereum nílò ààyè kan láti gbé ohun èlò àti àkóónú olùgbéejáde ńlá síbẹ̀. Bíi ti àwọn ọ̀rẹ́ wa ní Mozilla, ohun gbogbo níbí jẹ́ ìmọ̀-ìmọ̀ tí ó wà ní ṣíṣí sílẹ̀ tí ó sì ṣetán fún ọ láti mú un gbòòrò àti láti mú un dára sí i.
Tí o bá ní èsì èyíkéyìí, kàn sí wa nípasẹ̀ GitHub tàbí lórí olùpín Discord wa. Darapọ̀ mọ́ discord(opens in a new tab)