Àwọn ìṣètò ìlànà ati staaki aṣeelẹ
A gba o ni iyanjú lati mú ìṣètò ìlànà kan, páápa tí o ba je titun sii. Siṣẹda dapp to kojuosúnwọn nilo akojọpọ ìmọ̀ ẹ̀rọ. Ìṣètò ìlànà ní àwọn ẹ̀yà tí o nilo tabi pese ẹ̀to pulọọgin to rorun lati mú irinṣẹ ti o fẹrán.
Àwọn ìṣètò ìlànà yìí wa pèlú ọpọlọpọ àkànṣe iṣesi, bi:
- Àwọn ẹ̀yà láti ṣàfilọ́lẹ̀ àpẹẹrẹ blockchain agbègbè padà.
- Awọn ohun elo lati ṣajọ ati idanwo awọn adehun ọlọgbọn rẹ.
- Awọn afikun idagbasoke lati kọ ohun elo ti o dojukọ olumulo rẹ laarin iṣẹ akanṣe / ibi ipamọ kanna.
- Ṣiṣeto lati sopọ mọ àwọn netwọọki Ẹ́tẹ́ríọ́mù ati agbejade àwọn adehún ọlọgbọn, boyá sí ohún èlò alabẹlẹ tabi ara awon nẹtiwọọki ita gbangba Ẹ́tẹ́ríọ́mù.
- Pípín ifilọlẹ alailakoso - isopọ pèlú awon asayan èlò ipamọ bí IPFS.
966
Waffle
Ohún elo to dara julọ lati ṣayẹwo adehun ọlọgbọn. O le lo lasan tabi pẹlu Scaffol-eth tabi Hardhat.
TYPESCRIPTSOLIDITY
Ṣí Waffle278
Kurtosis Ethereum Package
Ohun elo irinṣẹ to da lori apoti fun ìròrùn sisétò àti alayipo fun testnet Ethereum opo onibaara fun ìdàgbàsókè dApp agbegbe, awokose àti fun àyèwò.
STARLARKPYTHON
Ṣí Kurtosis Ethereum PackageTYPESCRIPTSOLIDITY
Ṣí Hardhat2,666
Brownie
Ìpilẹ̀sẹ̀ ìdàgbàsókè àti ìdánwò tó dá lórí Python fún àwọn àdéhùn ọlọ́gbọ́n tó fojú sí Ẹ̀rọ Àìfojúrí Ethereum.
PYTHONSOLIDITY
Ṣí BrownieHTMLSHELL
Ṣí Epirus2,756
Create Eth App
Ṣẹda awọn ohun elo ti o lo agbara Ethereum pẹlu aṣẹ kan. Ó wá pẹ̀lú àwọn àkànṣe UI àti àwọn àwose DeFi ti o le yàn nínú wọn.
JAVASCRIPTTYPESCRIPT
Ṣí Create Eth App1,479
Scaffold-ETH-2
Ethers + Hardhat + React: gbogbo ńkán tí o nilo lati bere siṣeda awon afilọlẹ alailakoso to lo agbara nipase adehún ọlọgbọn.
TYPESCRIPTJAVASCRIPT
Ṣí Scaffold-ETH-21,973
Solidity template
Awose GitHub fún ohún èlò aṣesilẹ fún adehún ọlọgbọn Solidity rẹ. O ni afikun nẹtiwọọki agbegbe Hardhat, Waffle fún igbeyẹwo, Ethers fún iṣamulo wọlẹẹti ati bẹ́ẹ bẹ lọ.
TYPESCRIPTSOLIDITY
Ṣí Solidity template8,461
Foundry
Ohún èlò to yara kiakia, oniwońba, oni modula fún ṣiṣẹda afilọlẹ Ẹ́tẹ́ríọ́mù ti a ko pèlú Rust.
RUSTSHELL
Ṣí Foundry