Àwọn ìtọ́nisọ́nà Ethereum
Ṣé o fẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò Ethereum rẹ? Àwọn ìwé ìtọ́nisọ́nà yìí á ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀, á sì mú kó rọrùn fún ẹ láti mọ bí o ṣe lè lo ẹ̀rọ ìgbàlódé yìí.
Ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀
Báwo ni a ṣe lè "ṣẹ̀dá" àkántì Ethereum - Ẹnikẹ́ni le ṣẹ̀dá wọ́lẹ́ẹ́tì kan sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́. Ìwé ìtọ́nisọ́nà yìí á jẹ́ kí o mọ ibi tí o ti lè bẹ̀rẹ̀.
How to use a wallet - Learn how to send and receive tokens in your wallet and how to connect wallet to projects.
Àwọn ohun tó ṣe pàtàkì nípa ààbò
Báwo ni o ṣe le fagilé ìgbà láàyè àdéhùn ọlọ́gbọ́n sí owó crypto rẹ - tí o bá ṣàdédé rí ìdúnàádúrà kan tí o kò béèrè fún nínú wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ, ìtọ́sọ́nà yìí yóò kọ́ ọ bí o ṣe le dènà irú rẹ̀ láti má ṣẹlẹ̀ mọ́.
Báwo ní a ṣe le ṣe ìdánimọ̀ àwọn tọ́kẹ̀n ayédèrú — kíni àwọn tọ́kẹ̀n ayédèrú, báwo ní wọ́n ṣe le jẹ́ kí ara wọn dàbí ojúlówó, àti pé báwo ní a ṣe e le ṣe ìdánimọ̀ wọn làti dáàbò bo ara rẹ àti dènà kíkó sí páńpẹ́ ẹ̀tàn.
Lílo Ethereum
Bí o ṣe lè so àwọn tọ́kẹ̀n mọ́ ipele 2 - Ǹjẹ́ ìdúnàádúrà Ethereum wọ́n jù? Ṣẹ́ o ń rò bíbọ́ sí ojútùú ìgbélọsókè Ethereum tí à ń pè ní ipele 2s.
Bá a ṣe ń pààrọ̀ àwọn tọ́kẹ̀n - Ṣé o fẹ́ pààrọ̀ àwọn tọ́kẹ̀n rẹ fún òmíràn? Ìwé atọ́nà yìí á jẹ́ kí o mọ bí o ṣe lè ṣe é.