Bí o ṣe lè ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn owó ìgbàlódé
Ṣe o ni ìrẹwẹsi látí wá páṣípáárọ tí o sè àtòjọ gbogbo àwọn tọ́kẹ̀n áyànfẹ rẹ bi? O lè páárọ pùpọ júlọ nínù àwón tọ́kẹ̀n nípá lílo .
Páṣípáárọ tọ́kẹ̀n pẹlù páṣípáárọ áwọn ohùn-íní oriṣi mèjí tí o wá lorí nẹtíwọọkí Ethereum, fùn ápẹẹrẹ pípáárọ ẸTH fùn DÁI (an token). Ìláná náà yára gan o tùn jẹ olọwọ pókù. Ìwọ yoo ní látí nílo wọ́lẹ́ẹ́tì crypto látí páárọ àwón tọ́kẹ̀n.
Pátákí ṣáájù:
- ní , o le tẹle ìkẹkọ yí: Bí o ṣe lè: "Forùkọ́sílẹ" fún àkántí Ẹthereum
- fí owo sí wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ
1. So wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ mọ́ pasípààrọ̀ aláìlákóso (DEX) tí o yan
Diẹ nínù áwọn gbájùmo pàṣípààrọ̀ ni:
- Uniswap(opens in a new tab)
- Sushiswap(opens in a new tab)
- 1Inch(opens in a new tab)
- Curve(opens in a new tab)
Ṣó yanilẹ́nu ni? Kọ ẹkọ síì nípá kíní ìṣúná aláìlákóso (DeFi) jẹ átí bí írù áwọn pásípáárọ tuntun yí ṣè n sísẹ.
2. Yan àwọn tọ́kẹ̀n méjì tí o fẹ́ láti pààrọ̀ wọn
Fùn àpẹẹrẹ, ETH àti DAI. Rí i dájú pé o ní owó nínú ọ̀kan lára àwọn tọ́kẹ̀n méjì náà.
3. Tẹ iye awọn tọ́kẹ̀n ti o fẹ lati ṣowo ki o si tẹ paṣipaarọ
Pàsípáàrọ̀ náà yóò ṣírò iye tọ́kẹ̀n tó o máa gbà.
4. Ṣe ìdánilójú ìdúnàádúrà náà
Ṣàgbéyẹ̀wò kúlẹ̀kúlẹ̀ ìdúnàádúrà náà. Ṣàyẹ̀wò iye owó paṣipaarọ àti àwọn owó míì kó o lè yẹra fún àwọn ohun tí o le ṣẹlẹ̀.
5. Duro fun ki ìdúnàádúrà lati wa ni sise
O lè wo ìlọsíwájú ti ìdúnàádúrà lórí èyíkéyìí aṣàwárí blockchain. Ìgbésẹ̀ yìí kò gbọ́dọ̀ ju ìṣẹ́jú mẹ́wàá lọ.
Ìwọ yóò gba àwọn tọ́kẹ̀n tí a ṣe pàṣípààrọ̀ wọn láìfọwọ́yí nínú wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ ní kété tí a bá ṣe ìlànà ìdúnàádúrà náà.
Awon ibere gbogbo ìgbà
Ṣé mo lè fi ETH ṣe pàṣípààrọ̀ BTC láti inú wọ́lẹ́ẹ́tì mi?
Rárá o, o le ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn tọ́kẹ̀n tí ó jẹ́ àbínibí fún nẹtiwọọki Ethereum, bíi tọ́kẹ̀n ETH, ERC-20 tàbí NFTs. O le ṣe paṣipaarọ awọn ẹ̀dà "ti a fi sinu" ti Bitcoin ti o ngbe lori Ethereum.
Kí ni ìyàtọ̀ iye ọjà?
Ó jẹ́ ìyàtọ̀ tó wà láàárín iye tí o retí kí òṣùwọ̀n pàṣípààrọ̀ jẹ́ àti iye tó jẹ́ gangan.