Bí o ṣe lè so owó ìgbàlódé mọ́ ìpele kejì
Tí ọpọlọpọ súkéérefákééré bá wá lorí Ethereum, ó lè náni lówó gan-an. Ojùtù kan sí éyí ní látí ṣẹdá "áwón ipele" tuntun, to tumo si áwón nẹtíwọọkí òríṣíríṣí éyítí o n ṣíṣẹ ní áwọn ọna kanna bíi Ethereum fùnráráré. Áwọn wọnyí tí á npé ní Ipele 2s ṣẹ íranlọwọ látí dínkù ìfùnpọ átí íyé owo lorí Ethereum nípásẹ sísẹ áwọn ídùnádùrá ní owo kékéré, átí nípá títọjù ábájádé tí áwọn wọnyí níkan lorí Ethereum ní gbogbo ígbá. Bí èléyí, àwọn ipele 2s yíì jẹ kí á ṣé ìdùnádùrá pélù ìyárá tí o pọ sí àtí àwọn ìdíyélè to díńkù. Ọpọlọpọ áwọn ísé àkánṣé crypto olokíkí ń lọ sí ipele 2s nítorí àwọn àǹfààní wọnyí. Ọná tí o rọ́rùn jùlọ làtí gbé àwó̩n tọ́kẹ̀n látí Ẹthereum sí ipele 2 ni láti lo àfárá kan.
Pátákí ṣáájù:
- ní wọ́lẹ́ẹ́tì crypto, o lè tẹ̀lé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí: Bí o ṣe lè: "Forùkọ́sílẹ" fún àkántì Ẹthereum
- fí owo sí wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ
1. Pinnu nẹ́tíwọọkìí ipele 2 wo ni o fé látí lo
O lé kọ́ èkọ́ sìí nìpá àwọ́n ìsé àkánṣé ọrìsírìsí àtí àwọn ọná àsopọ́ pàtákí lórí ojú-ìwé ipele 2.
2. Ló sí àfárá tí o yán
Àwón gbájúmó̩ ipele 2s ni:
- Afárá Arbitrum(opens in a new tab)
- Afárá Optimism(opens in a new tab)
- Afárá network Boba(opens in a new tab)
3. Sopọ́ sí afárá pélù wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ
Ríi dájú pé wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ ní ìsopò mó nẹ́tíwọọkí Mainnet Ethereum. Tí kí bá ṣé bé, òjú òpó wẹẹbú yo tọ́ ọ láífọ̀wọ́yí látí yí àwọn nẹ́tíwókí pàdá.
4. Sọ́ pátó ìyé kí o ṣí gbé àwọn òwó nàá
Ṣe atunyẹwo iye tí waa gba pádà lori nẹtiwọọki ipele 2 ati owó iṣẹ́ látí dena ìyàlẹnu ti o ko lero.
5. Ṣaridaju idunadura naa ninu wọlẹẹti rẹ
Ìwọ yóò ní láti san owó kan ní ìrísí ETH fún síṣe ìdúnàádúrà náà.
6. Dúró fún owó rẹ láti di gbígbé
Ìlànà yii kò gbọ́dọ̀ gbà ju ìṣẹ́jú mẹ́wàá lọ.
7. Fi nẹtiwọọki ipele 2 ti o yan sí wọlẹẹti rẹ (kò pọn dandan)
O le lò chainlist.org(opens in a new tab) látí wa alaye nẹtiwọọki RPC. Lọ́gán tí nẹtiwọọki na bati wa ni afimọ ti idunadura si ti parí, wàá ri àwọn token naa ninu wọlẹẹti rẹ.
Awon ibere gbogbo ìgbà
Tí mo ba ní owó nínú pàsípáárọ kan ńko?
O lè ní anfaani látí ṣe iyọkuro sí àwọn ipele 2 ni táàra látí ori pàsípaarọ. Wo abala "Gbe sí ipele 2" tioju-iwe Ipele 2 wa fún alaye si.
Ńjẹ mo le pada sí Ethereum mainnet lẹyin ìgbà ti mo so token mi mọ L2?
Bẹ́ẹ̀ni, o le máa gbe owó rẹ pada sí mainnet pẹ̀lú lilo afara kan naa.