Ṣiṣe ipade kan
Ṣe akoso ni kikún.
Ṣe nóòdu rẹ fúnra rẹ.
Dí aláṣẹ kikún pèlú didàbo bo nẹtiwọọki. Di Ẹ́tẹ́ríọ́mù.
ki ni ṣe o tumọ si "lilo nóòdu"?
Lo softiwia.
Tí a mọ sí 'onibaara', softiwia yí yoo ṣe igbasile ẹda blockchain Ethereum yoo sitún ṣe idanilojú ífẹsẹmulẹ gbogbo bulọọku, yòó tún ṣe imudojuiwon rẹ pèlú awon bulọọku tuntun ati àwọn idunadura, yòó tún ran awọn yòóku lọwọ lati ṣe igbasile ati imudojuiwon ẹda ti wọn naa.
Pèlú ẹ̀yà ẹ̀rọ.
A ṣe Ethereum lati ṣisẹ nóòdu lori awọn kọmputa olumulo apapọ. O le lo komputa aladani ṣùgbọ́n ọpọlọpọ olumulo ma ń lo komputa aladanla fún ija gèére iṣẹ nóòdu.
Nigbati o ba wà lórí ayélujára.
Lilo nóòdu Ẹ́tẹ́ríọ́mù le ṣòro ní akọkọ, ṣùgbọ́n o kan jẹ lilo softiwia onibáàra ni lemọlemọ pèlú wíwà lojú opo intanẹẹti. Tí o ko ba sí ní oju-opo, nóòdu yòó wa ni aiṣiṣẹ títí yoo fí pada si oju-opo, yòó sí gba àwọn iyàtọ titún to ba wa.
Táàni o le lo nóòdu?
Gbo èniyan! Nóòdu ko kan wa fún àwọn oluṣayẹwo . Ènikèni le lo nóòdu - koda o ko nilo lati ní ETH.
Ó kò ni lati fí ETH ki o to le lo nóòdu. Kódà, gbogbo nóòdu miiran lori Ẹ́tẹ́ríọ́mù ní àwọn oluṣayẹwo a se iṣiro fún.
O lè ma gba èrè oni owó tí àwọn oluṣayẹwo gba, ṣùgbọ́n àwọn èrè miiran wa pèlú lilo nóòdu fún oluṣamulo Ẹ́tẹ́ríọ́mù to ni lati gbeyewo, to pelu aṣiri, ààbo, idinkún gbigbarale àwọn olupín ẹlẹ́gbẹ́-kẹta, títako ifòfinde ìlera to dára síi àti ṣíṣe aláìlákóso nẹ́tíwọọkì.
Níní nóòdu tirẹ túnmọ sí pe ó kò nilo lati fí alaye síta nipa ipo nẹtiwọọki tí olupin ẹlẹ́gbẹ́-keta pese.
Má ṣe gbẹkẹlé. Ṣe aridaju.
Ìdí tí a fí n lo nóòdu?
Ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀
Nì àwọn ọjọ́ ibẹ̀rẹ̀ nẹtiwọọki, olúṣamulo nílo lati ni ibaṣepọ pèlú ìlà-kọmandi lati le lo nóòdu Ẹ́téríómù kán.
Tí eyi bajẹ ifẹran rẹ, tí osi ni ìmọ̀ rẹ, yẹ àwọn iwé ikọṣemọse wa wò.
Bayìí a ní NóòduDApp, tí o je sọftiwìá ọfẹ to ṣi silẹ o sí fún àwọn aṣamulo ní irírí afilọlẹ nigbati wọn ba ń ṣe akoso nóòdu wọn.
Pèlú itẹ ni wọnba, o le ṣeda nóòdu rẹ tí yoo sì mọ ṣiṣẹ.
DAppNode jẹ kí o rọrún fún àwọn aṣamulo lati lo nóòdu kikún, ati ati àwọn nẹtiwọọki , lai nilo ìlà-komandi. Eyi jọ kí o rorún fún gbogbo ènìyan lati kopa ati ṣeda nẹtiwọọki ti alailakoso dáàda.
Mú idawọle rẹ
Òó nilo àwọn ẹ̀rọ lati bẹ̀rẹ̀. O ṣeeṣe ki o lo afilọlẹ nóòdu lori komputa rẹ ṣugbọn lilo ẹ̀rọ ifaraji yoo daaju fún nóòdu rẹ ti ipa re yoo si kéré lori komputa ara ẹni rẹ.
Nigbati o ba ń mú ẹ̀rọ, rípe ṣéèni na ń gboro si ti yóò si nilo atunṣe orekóóre. Ìgbéga àwọn ẹ̀yà ṣì lè ṣe ìrànlọ́wọ́ ìdádúró ìwúlò fún ìtọ́jú nódù.
Ra èyí tó kún
Ra ẹ̀rọ amúṣẹ́yá lọ́wọ́ àwọn òǹtajà fún ìrírí ìmúniwọlé tó rọrùn.
- Kò nílò àpilẹ̀kọ.
- Ètò àfojúrí pẹ̀lú ìfihàn àsopọ̀ aláwòrán.
Kò nílò ìlà-àṣẹ.
Ko ti tire
Àṣayan olówó pọku ati alàdáni fún àwọn olumulo akọṣemọṣẹ.
- Wá àwọn ẹ̀yà tirẹ.
- Fí NóòduDApp sí ori ẹ̀rọ.
- Tabi, mú OS rẹ àti àwọn onibáàra rẹ.
Ko ti tire
Ẹsẹ kini - Ẹ̀yà àfojúrí
Specs to kéré jù lọ
RAM merin - mejọ GB
SSD TB méjì
SSD ṣe pàtàkì fún àwọn ìyára kíkọ tí a béèrè.
Tí a dábàá
- Intel NUC, gen ìkẹ́jẹ tàbí kó ja julo
x86 isise
- Internet alasopo pẹ̀lú waya
Ko pọn dandan, ṣùgbọ́n ó ń pèsè ìṣètò tó rọrùn àti ìsopọ̀ tó dúró déédéé
- Ìfihàn ìbòjú àti àtẹ bọ́tìnnì
Àyàfi tí ó bá ń lọ DAppNode, tàbí ssh/ìṣètò aláìlórí
Ẹsẹ kejì - Sofitiwia
Àṣàyàn kini - DAppNode
Tí ó bá ti ṣe tán pẹ̀lú ìṣètò ẹ̀rọ rẹ, ètò ìmúṣiṣẹ́ DAppNode wá láti gba sì orí kọ̀ǹpútà rẹ àti sí orí SSD titun pelu USB.
Àṣàyàn kejì - láìní Àṣẹ
Fún ìṣàkóso tótó, àwọn olúmùlò tí wọn ní ìrírí lè feran láti lọ láìní àṣẹ.
Wo àwọn ìwé olùgbéejáde fún àlàyé síwájú sí i lórí bíbẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú yíyàn oníbàárà.
Wá àwọn oluranlọwọ́
Ojú opo ayẹ́lujára bíi Discord tàbí Reddit jẹ ilẹ́ fún òpò àwọn olùṣeda awujo tí wọ ń fẹ lati ran o lọwọ́ pẹ̀lú eyikeyi idojukọ tí o ní.
Máṣe dàáṣe. Tí o ba ní ìbeere o ṣee ṣe kí ẹnìkan fún o ní èsì níbi.
Kíkà síwájú síi
Fí ETH rẹ dógò
Botilẹjẹpẹ ko pọn dandan, pèlú lilo nóòdu o tí súnmọ didokòwò pèlú ETH rẹ lati jẹ èrè bakan naa ati lọwọsi ẹka ọ̀tọ̀ ti ààbo Ẹ́tẹ́ríọ́mù.
O ń gbero lati dokowò bí?
Lati ṣe ijafafa olusayẹwo rẹ ní kikun, o nilo o kere ju RAM mẹẹdogun gigabaiti, ṣugbọn mejilelọgbọn yóò dara ju lo, pèlú CPU 6667+ lori cpubenchmark.net(opens in a new tab). A tún dábàá pé kí àwọn olùdókòwò ní àǹfààní láti lo ìkànnì íńtánẹ́ẹ̀tì alágbàrá tí kò ní ààlà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ko pọn dandan.
EthStaker ṣàlàyé lẹ́kúnrẹ́rẹ́ nínú ètò oní wákàtí kan yìí - Bi a ti n ra ẹ̀rọ oluṣayẹwo Ẹ́tẹ́ríọ́mù(opens in a new tab)
Alaye lori Raspberry Pi (ARM processor)
Àwọn Raspberry Pi fuyẹ wọn sí jẹ komputa tí ko gunpa, ṣugbọn wọ ni opin sí ipa ti wọn le ṣe fún ise nóòdu rẹ. Botilẹjẹpẹ wọn o ṣe gbara le fún idokowo, wọn jẹ aṣayan to tayọ ti kosí wọn fún nóòdu ti ara eni, pèlú RAM láàrin mẹrin sí mẹjọ.
- Ẹ́tẹ́ríọ́mù lori akọsile ARM(opens in a new tab) - Kọ lati ṣeto nóòdu pèlú ìlà-kọmandi lori Raspbery Pi
- Lo nóòdu pèlú Raspberry Pi - Tẹlẹ nibí toba jẹ pẹ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ lo nifẹ si