Rékọjá sí àkóónú àkọ́kọ́

Ṣayẹwo adirẹsi adehun afipamo

Eyi ni adirẹsi fun adehun idokowo Ethereum. Lo oju-iwe yii lati jẹrisi pe o nfi owo ranṣẹ si adirẹsi ti o tọ́ nigbati o ba dokowo.

Eyi kii ṣe ibiti o ti dokowo

Lati dokowo ETH rẹ o gbọdọ lo ọja launchpad ki o tẹle awọn ilana naa. Fifiranṣẹ ETH si adirẹsi ti o wa ni oju-iwe yii kii yoo jẹ ki o jẹ oludokowo ati pe yoo ja si idunadura to kuna. Díẹ̀ si lórí dókòwò

Dokowo pelu launchpadopens in a new tab

Ṣayẹwo awọn orisun wọnyi

A nireti pe ibẹ gbodo ni ọpọlọpọ awọn adirẹsi ayederu ati awọn jibiti. Lati wa ni ailewu, ṣayẹwo adiresi adehun idokowo ti o nlo si adirẹsi to wa ni oju-iwe yii. A gba o nimoran pe ki o ṣayẹwo rẹ pẹlu awọn orisun igbẹkẹle miiran paapaa.

Ṣayẹwo adirẹsi adehun afipamo

Jẹrisi lati ṣafihan adirẹsi

Ǹjẹ́ ojú-ìwé yìí ṣe ìrànlọ́wó?