Kí ní didokowò alapapọ?
Idokowò alapapọ ní ìlànà ibaṣepọ lati jẹ kí àwọn oni iye ETH kereje gbimọpọ lati ní ETH mejileelọgbọn tí wọn nilo làti ṣeto akojọpọ kókóró oluṣayẹwo. Iṣẹ́ ìdokowò apapọ ko ba ìlànà ìbílẹ̀ mu làárín ìlànà náà, ìdí ní yii ti ojutu fí wà lori ìlànà miirań láti kojú èyí.
Àwọn idokowò pupọ ma ń ṣiṣẹ pọ pẹ̀lú lilo adehún ọlọgbọn, nibití owó lẹ di fifipamọ sí ori adehún ọlọgbọn, eyi tí yoo ṣakoso ati itọpinpin idokowò rẹ, bakan na fùn o ni tọ́kẹ̀n ti o ṣe deede iye owó rẹ. Àwọn àkójọpọ̀ mìíran le ma lo adehún ọlọgbọn ti wọn sí lo ìdúnàádúrà mìíràn dipo rẹ.
Kí ní idi lati dokowò pẹ̀lú àkójọpọ̀?
Ní afikún si àwọn àǹfààní ti ati sọ tẹle ninu ọ̀rọ̀-agbekale idokowò, didokowò nipasẹ àkójọpọ̀ wa pẹ̀lú àwọn èrè ailẹgbẹ.
Idena lati wọle kéré
Not a whale? No problem. Most staking pools let you stake virtually any amount of ETH by joining forces with other stakers, unlike staking solo which requires 32 ETH.
Dokowò loni
Staking with a pool is as easy as a token swap. No need to worry about hardware setup and node maintenance. Pools allow you to deposit your ETH which enables node operators to run validators. Rewards are then distributed to contributors minus a fee for node operations.
Àwọn tọ́kẹ̀n idokowò
Many staking pools provide a token that represents a claim on your staked ETH and the rewards it generates. This allows you to make use of your staked ETH, e.g. as collateral in DeFi applications.
Àfiwé pẹ̀lú àwọn àṣàyàn mìíràn
Home staking
Pooled staking has a significantly lower barrier to entry when compared to home staking, but comes with additional risk by delegating all node operations to a third-party, and with a fee. Home staking gives full sovereignty and control over the choices that go into choosing a staking setup. Stakers never have to hand over their keys, and they earn full rewards without any middlemen taking a cut.
Kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa ìdókòwò aládaṣeAba bi iṣẹ (saas)
Àwọn yìí ní àfínkúpọ̀ nítorí pé àwọn olùdókòwò kò mú sọfitiwia olùsàyẹ̀wò ṣiṣẹ́ fúnra wọn, ṣùgbọ́n kìí ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú àwọn aṣàyàn àkójọpọ̀, SaaS nílò fífi méjìlélọ́gbọ̀n ETH pátápátá sílẹ̀ láti mú olùsàyẹ̀wò kan ṣiṣẹ́. Èrè ń kó pọ̀ fún olùdókòwò, àti pé ó sábà máa ń ní owó sísan ti oṣooṣù tàbí ìdókòwò mìíràn láti lò iṣẹ́ náà. Tí o bá fẹ́ àwọn kọ́kọ́rọ́ olùsàyẹ̀wò tìrẹ àti pé o ń wá láti fi o kere ju méjìlélọ́gbọ̀n ETH dókòwò, lílo olùpèsè SaaS lè jẹ́ àṣàyàn tó dára fún ọ.
Àlàyé síi nípa ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́Àwọn nǹkan tó yẹ kó o ronú lé lórí
Ìdokowó alapapọ ko sí ní ìlànà Ẹ́tẹ́ríọ́mù, ṣùgbọ́n bi àwọn oluṣamulo se beere fun didokowò pẹ̀lú iye ti ko to ETH mejilelọgbọn, àwọn ọpọlọpọ ojutu si tí wa fún wọn.
Àkójọpọ̀ kọọkan ati awọn irinṣẹ tabi awọn iwe adehun ọlọgbọn ti wọn lo ti a ti kọ nipasẹ awọn ẹgbẹ oriṣiriṣi, ati pe ọkọọkan wa pẹlu awọn anfani ati awọn ewu. Àwọn àkójọpọ̀ gba olúṣamulo láàye lati paarọ ETH fún tọ́kẹ̀n to ṣe deede ETH idokowò. Tọ́kẹ̀n wúlò nitori pe yoo je ki àwọn olúṣamulo paaro iyekiye ETH sì deede iye èrè tọ́kẹ̀n tí o kojọ nípaṣe didokowò tí o so mọ okunfa idokowò ETH(ati ni idakeji) lori pasiparo alailakoso botiwulẹ jẹ pẹ iye ETH idokowò gangan wa lorí ipele apapọ. Eyi túnmọ sí pe ipasípáàrọ sẹhin siwaju lati didokowò-ETH elèrè ati "ojulowo ETH" yara, rorún osí tún wa ní gbogbo iye ETH méjìlélọ́gbọ̀n.
Àwọn tọ́kẹ̀n ìdokowó-ETH má ń ṣe bi katẹẹli níbítí iye ETH ìdokowò toba pọ yoo wa ní akoso àwọn ileṣe alakoso ààrin dípò ifọnka sí ọdọ gbogbo eniyan olominira. Eyi ṣẹda awọn ipo fun ìfòfinde tabi yiyo iwulo. Gbedẹkẹ didokowò gbọdọ jẹ lilo oluṣayẹwo lati ọdọ àwọn eniyán lori ẹrọ wọn ni igbakigba.
Díẹ̀ si lori ewu fifi tọ́kẹ̀n dokowò(opens in a new tab).
Atọka ẹya ni a lo ni isalẹ yii lati ṣafihàn àwọn agbara tabi aipeye tí àkójọpọ̀ ìdókòwò tí a ṣàtòjọ lè ni. Lo abala yi gẹgẹ bí itọka fún bí a ṣe ṣàlàyé àwọn ẹya wonyi ti o ba fẹ mú àkójọpọ̀ lati darapọ mọ.
- Ṣii orisun
- A ti ṣàyẹ̀wò rẹ̀
- Ẹ̀bùn àṣìṣe ẹ̀rọ
- A ti danwò nínú ìjà
- Àìní ìgbẹ́kẹ̀lé
- Nódù aláìní ìyọ̀nda
- Onírúurú àtìṣe
- Onírúurú àtìṣe
- Tọ́kẹ̀n alásọdowó
Ṣii orisun
Kóòdù pàtàkì jẹ́ àrọ́wọ́ọ́tó ní ìdá ọgọ́rùn-ún ó sì wà fún gbogbo ènìyàn láti ṣe àtúnṣe àti lò
Ṣii orisun
Orísun tó wà ní ìpadé
Ṣ'awarí àwọn àkójọpọ̀ idokowò
Àwọn aṣayàn pọ loriṣirṣi lati ran o lọwọ pẹ̀lú iṣeto rẹ. Lo àwọn olutọka òkè yi fún iranlọwọ ilo àwon irinṣẹ isale wọnyi.
Jọ̀wọ́ ṣàkíyèsí pàtàkì yíyan iṣẹ́ tó mú yiyatọ onibaara ni ọkunkundun, nitori pe yòó je ki ààbo nẹtiwọọki nipọn si, yòó si ṣe adinku ewu. Àwọn iṣẹ́ tí wọn ni ẹri kikere ilo onibàára ni itọkasi "execution client diversity" ati "consensus client diversity."
Ní àbá irinṣẹ idokowò tí a padanu? Boju wo àwọn ìlànà kikojọ ọja lati mo bi wọn ba dangajia, ki o ṣi fa won kale fún àtúnyẹ̀wò.
Awon ibere gbogbo ìgbà
Kíkà síwájú síi
- The Ethereum Staking Directory(opens in a new tab) - Eridian and Spacesider
- Staking with Rocket Pool - Staking Overview(opens in a new tab) - RocketPool docs
- Staking Ethereum With Lido(opens in a new tab) - Lido help docs