Rékọjá sí àkóónú àkọ́kọ́

Ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́ kan

  • Awọn adari ero nodu ẹgbẹ-kẹta n sakoso iṣẹ ti onibara olufọwọsi rẹ
  • Aṣayan nla fun ẹnikẹni ti o ni 32 ETH ti ko ro lorun lati dojuko idiju imo-ero ti yoo ba pade nipase mimu nodu kan sise
  • Din igbẹkẹle ku, ki o ṣetọju abojuto awọn kokoro yiyọ owo kuro

Kini idokowo gege bi iṣẹ kan?

Idokowo gege bi iṣẹ kan ("Saas") duro fun ẹya kan ti awọn iṣẹ idokowo ti o fi 32 ETH dokowo fun olufowosi, ṣugbọn gbe awon ise nodu fun adari ero ẹnikẹta. Ilana maa n saba pelu itonisona nipa iseto akoko, pelu ipilese kokoro ati fifi owo si, leyin naa gbigbe awon kokoro wiwole re sori adari ero. Eyi gba iṣẹ naa laaye lati mu olufowosi rẹ sise fun o, nigbagbogbo fun owo sisan ni oṣooṣu.

Kini idi fun didokowo pẹlu iṣẹ kan?

Ilana Ethereum ko satilẹyin gbigbe ise idokowo fun elomiiran, nitorinaa awọn iṣẹ wọnyi ti je ipese lati yanju ibeere yii. Ti o ba ni 32 ETH fun idokowo, ṣugbọn ko ro e lorun lati sise pẹlu ohun elo, awọn iṣẹ SaaS gba ọ laaye lati gbe ise to le ju nibe fun elomiiran nigbati o ba n gba awon ere bulooku.

Olufowosi tirẹ

Deposit your own 32 ETH to activate your own set of signing keys that will participate in Ethereum consensus. Monitor your progress with dashboards to watch those ETH rewards accumulate.

O rọrun lati bẹrẹ

Forget about hardware specs, setup, node maintenance and upgrades. SaaS providers let you outsource the hard part by uploading your own signing credentials, allowing them to run a validator on your behalf, for a small cost.

Ṣe adinku ewu rẹ

In many cases users do not have to give up access to the keys that enable withdrawing or transferring staked funds. These are different from the signing keys, and can be stored separately to limit (but not eliminate) your risk as a staker.

Àfiwé pẹ̀lú àwọn àṣàyàn mìíràn

Home staking

Àwọn ohun tó jọra níbẹ̀ ni àwọn kọ́kọ́rọ́ olùyẹ̀wò tìrẹ láì nílò láti ṣíṣakójọ owó, ṣùgbọ́n pẹ̀lú SaaS, o ní láti gbẹ́kẹ̀lé ẹnì kẹta, tó lè hùwà ọ̀daràn tàbí di ẹni àkọlù tàbí tí òfin kálọwọ́kò. Tí àwọn àbá ìgbẹ́kẹ̀lé wọ̀nyí tàbí àwọn ewu alákóso bá ń jẹ́ àníyàn fún ọ, ìdiwọ̀n góólù ti ìdókòwò tó ní àkóso ara ẹni ni ìdókòwò aládaṣe.

Kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa ìdókòwò aládaṣe

Ìdókòwò alápapọ̀

Àwọn yìí ní àfínkúpọ̀ nítorí pé o sábà ń gbẹ́kẹ̀ lé ẹlòmíràn láti ṣiṣẹ́ olùyẹ̀wò, ṣùgbọ́n, kì í ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú SaaS, ìdókòwò àkójọpọ̀ ń jẹ́ kí o lè kópa pẹ̀lú iye kékèké ETH. Tí o bá ń wá láti dókòwò pẹ̀lú iye tó kéré sí ETH méjìlélọ́gbọ̀n, rò láti ṣàyẹ̀wò àwọn wọ̀nyí.

Láti mọ̀ síi nípa ìdókòwò alápapọ̀

Àwọn nǹkan tó yẹ kó o ronú lé lórí

Iye awọn olupese SaaS n dagba si lati ṣe iranlọwọ fun ọ lati dokowo ETH re, ṣugbọn gbogbo wọn ni awọn anfaani ati eewu won. Gbogbo awọn aṣayan SaaS nilo awọn ero igbẹkẹle afikun ni akawe si idokowo ile. Awọn aṣayan SaaS le ni afikun koodu fun awọn onibara Ethereum ti ko wa ni ṣiṣi tabi se sayewo. SaaS tun ni ipa iparun lori alailakoso nẹtiwọọki. To da lori iṣeto, o le ma ṣakoso olufowosi rẹ - adari ero le ṣe alaisooto nipa lilo ETH rẹ.

A lo awọn atọka abuda ni isalẹ lati ṣafihan awọn agbara to ga si awọn ailera ti olupese SaaS ti a satojo re le ni. Lo abala yii bi itọkasi fun bawo ni a ṣe ṣalaye awọn abuda wọnyi nigbati o n yan iṣẹ kan lati ṣe iranlọwọ pẹlu irin-ajo idokowo rẹ.

  • Ṣii orisun
  • A ti ṣàyẹ̀wò rẹ̀
  • Ẹ̀bùn àṣìṣe ẹ̀rọ
  • A ti danwò nínú ìjà
  • Eyi ti ko nilo iyọọnda
  • Onírúurú àtìṣe
  • Onírúurú àtìṣe
  • Àkàtà ara ẹni

Ṣii orisun

Kóòdù pàtàkì jẹ́ àrọ́wọ́ọ́tó ní ìdá ọgọ́rùn-ún ó sì wà fún gbogbo ènìyàn láti ṣe àtúnṣe àti lò

Ṣii orisun

Orísun tó wà ní ìpadé

Ṣawari awọn olupese iṣẹ idokowo

Ni isalẹ, a ni awọn olupese SaaS to wa. Lo awọn atọka to wa loke lati ṣe iranlọwọ fun ọ nipasẹ awọn iṣẹ wọnyi

Àwọn ọjà àti iṣẹ́ ni a ṣe àkójọ bíi ìrọ̀rùn fún àwùjọ Ethereum. Fífi ọjà tàbí iṣẹ́ kan kún un kò jẹ́ aṣojú ìfọwọ́síláti ọ̀dọ̀ ẹgbẹ́ ìkànnì ethereum.org, tàbí Àjọ Ethereum.

Awọn olupese SaaS

Jọwọ ṣakiyesi pataki ti atilẹyinoniruuru onibaarabi o ṣe mu aabo nẹtiwọọki dara si, ati adinku eewu rẹ. Àwọn iṣẹ́ tí wọn ni ẹri kikere ilo onibàára ni itọkasi "execution client diversity" ati "consensus client diversity."

Awọn Olupilese Kokoro

Ni aba kan fun olupese iṣẹ bi idokowo ti a padanu? Boju wo àwọn ìlànà kikojọ ọja lati mo bi wọn ba dangajia, ki o ṣi fa won kale fún àtúnyẹ̀wò.

Awon ibere gbogbo ìgbà

Kíkà síwájú síi

Ǹjẹ́ ojú-ìwé yìí ṣe ìrànlọ́wó?