What is home staking?
Home staking is the act of running an Ethereum node connected to the internet and depositing 32 ETH to activate a validator, giving you the ability to participate directly in network consensus.
Home staking increases the decentralization of the Ethereum network, making Ethereum more censorship-resistant and robust against attacks. Awọn ọna idokowo miiran le ma ṣe iranlọwọ fun nẹtiwọọki naa ni awọn ọna kanna. Home staking is the best staking option for securing Ethereum.
Nodu Ethereum kan ni onibaara ipele mimusise, ati onibaara ipele ifohunsokan. Awọn onibaara wọnyi jẹ sofitiwia ti o ṣiṣẹ pọ, pẹlu eto ti o wulo ti awọn kokoro iwole, lati jẹrisi si awon idunadura ati bulooku, jẹrisi olori ilana naa, ijerisi akopo, ati awon bulooku idabaa.
Home stakers are responsible for operating the hardware needed to run these clients. Idabaa gidi wa pe ki o lo ero to wa fun eyi nikan ti wa dari lati ile–eleyii je anfaani pataki si ilera netiwooki naa.
A home staker receives rewards directly from the protocol for keeping their validator properly functioning and online.
Why stake home?
Home staking comes with more responsibility but provides you with maximum control over your funds and staking setup.
Gba ETH tuntun
Earn ETH-denominated rewards directly from the protocol when your validator is online, without any middlemen taking a cut.
Ìṣàkóso lẹ́kunrẹ́rẹ́
Keep your own keys. Choose the combination of clients and hardware that allows you to minimize your risk and best contribute to the health and security of the network. Third-party staking services make these decisions for you, and they don't always make the safest choices.
Aabo nẹtiwọọki
Home staking is the most impactful way to stake. By running a validator on your own hardware at home, you strengthen the robustness, decentralization, and security of the Ethereum protocol.
Considerations before home staking
As much as we wish that home staking was accessible and risk free to everyone, this is not reality. There are some practical and serious considerations to keep in mind before choosing to home stake your ETH.
Àfiwé pẹ̀lú àwọn àṣàyàn mìíràn
Aba bi iṣẹ (saas)
Pẹlu àwọn olùpèsè SaaS, o ṣì nílò láti fi méjìlélọ́gbọ̀n ETH sílẹ̀, ṣùgbọ́n o kò nílò láti ṣiṣẹ́ ohun èlò. Nípa ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú wọn, o máa ní àṣẹ sí àwọn kọ́kọ́rọ́ olùyẹ̀wò rẹ, ṣùgbọ́n o tún nílò láti ṣàjọpín àwọn kọ́kọ́rọ́ wíwọlé rẹ kí oníṣẹ́ náà lè ṣiṣẹ́ dípò olùyẹ̀wò rẹ. Èyí ń ṣàfikún ipele ìgbọ́kànlé kan tí kò sí nípò nígbà tí o bá ń mú ohun èlò tirẹ̀ ṣiṣẹ́, èyí tí kò rí bẹ́ẹ̀ nínú ìdókòwò àdáṣe ní ilé. SaaS kò ṣèrànwọ́ tó pẹ̀lú pínpín nódù káàkiri àwọn àgbègbè. Bí o kò bá fẹ́ràn láti mú ohun ẹ̀rọ ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n o ṣì ń wá láti fi ETH méjìlélọ́gbọ̀n sílẹ̀, lílo olùpèsè SaaS lè jẹ́ àṣàyàn tó dára fún ọ.
Àlàyé síi nípa ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́Ìdókòwò alápapọ̀
Ìdókòwò àdáṣe ní ìlọ́wọ́sí tó ga ju ìdókòwò pẹ̀lú iṣẹ́ àkójọpọ̀ kan, ṣùgbọ́n ó ń fún ni ní àṣẹ pátápátá sí àwọn èrè ETH, àti àṣẹ pátápátá lórí ìṣètò àti ààbò olùyẹ̀wò rẹ. Ìdókòwò àkójọpọ̀ ní ìsọ́kànsí tó kéré jùlọ fún ìbáṣepọ̀. Àwọn olùṣàmúlò lè fi iye kékèké ETH dókòwò, wọn kò nílò láti ṣẹ̀dá àwọn kọ́kọ́rọ́ olùyẹ̀wò, àti wọn kò nílò àwọn ìbéèrè fún ohun ẹ̀rọ ju àsopọ̀ mọ́ íńtánẹ́ẹ̀tì. Àwọn tókẹ̀n ìsọdowó ń jẹ́ kí o lè yọkúrò nínú ìdókòwò kí èyí tó ṣiṣẹ́ ní ipele ìlànà. Tí o bá nífẹ̀ẹ́ sí àwọn àbùdá wọ̀nyí, ìdókòwò àkójọpọ̀ lè jẹ́ aṣayan tó dára fún ọ.
Láti mọ̀ síi nípa ìdókòwò alápapọ̀Bi o ṣe n ṣiṣẹ
O ní láti ní kọ̀ǹpútà afojúrí: o ní láti mú ǹoódu ṣiṣẹ́ láti dókòwò
Ṣepọ̀ mọ́ ṣíṣiṣẹ́ ipele oníbàárà
Ṣepọ̀ mọ́ ipele ìpohùnpọ̀ oníbàárà
Pilẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé kí o sì fi sí orí oníbàárà olùṣàyẹ̀wò rẹ
Ṣàbójútó kí o sì ṣetọ́jú nòódu rẹ
Lakoko ti o n ṣiṣẹ lọwọ, wa gba awon ere ETH, eyiti yoo j ifipamọ ni igba kọọkan sinu adirẹsi yiyọ owo kuro re.
Ti o ba fẹ, o le jade gege bi olufowosi kan eyiti o yọ awon ibeere kuro nipa wiwa lori ayelujara, ati da eyikeyii ere siwaju sii duro. Owo re yoku yoo je gbigba kuro sinu adirẹsi yiyọ owo kuro ti o fi kale nigba iseto.
Díẹ̀ si lori yiyọ kuro idokowò
Bibẹrẹ lori Launchpad Idokowo
Launchpad idokowo je ohun elo orisun gbangba ti yoo re ọ lowo lati di oludokowo. Yoo tọ e sona nipa yiyan awọn onibaara rẹ, pilese awon kokoro re ati fifi ETH sinu adehun afipamo idokowo. A pese atojo ayẹwo lati rii daju pe o ti se ohun gbogbo to ye ki o se lati seto olufowosi re lailewu.
Olùyẹ̀wò aládaṣe gbọdọ̀ ṣe àyẹ̀wò ètò-iṣẹ́ wọn àti ìṣiṣẹ́ si lórí Holesky testnet ṣáájú fífowó si. Rántí pé dandan ni láti mú oníbàárà kékeré nítorí yòó ṣe ààbò nẹ́tíwọọkì tó dájú àti dín ewu rẹ kù.
Tí o ba ní ìfọkàbalẹ lori rẹ, o le ṣe gbogbo ńkan ti o nílo sì ori ila kọmandi pèlú Staking Lauchpad ni kan.
Láti mú já geere, ṣàyẹ̀wò àwọn irinṣẹ́ àti ìtọ́sọ́nà tí yóò ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ẹ pèlú Staking Launchpad làti ṣàgbékalẹ̀ àwọn oníbàárà rẹ ní ìrọ̀rùn.
Kini o ni lati ro pẹlu nodu ati awọn irinṣẹ iseto onibaara
There are a growing number of tools and services to help you home stake your ETH, but each come with different risks and benefits.
A lo awọn atọka abuda ni isalẹ lati ṣafihan awọn agbara to ga tabi ailera ti irinṣẹ idokowo ti a ṣe akojọ le ni. Lo abala yi gẹgẹ bí itọka fún bí a ṣe ṣàlàyé àwọn abuda wonyi nigba ti o ba mú awon irinse re lati ran o lowo pelu irin ajo idokowo re.
- Ṣii orisun
- A ti ṣàyẹ̀wò rẹ̀
- Ẹ̀bùn àṣìṣe ẹ̀rọ
- A ti danwò nínú ìjà
- Àìní ìgbẹ́kẹ̀lé
- Eyi ti ko nilo iyọọnda
- Ọ̀pọ̀-oníbàárà
- Àkàtà ara ẹni
- Ẹ̀dínwó
Ṣii orisun
Kóòdù pàtàkì jẹ́ àrọ́wọ́ọ́tó ní ìdá ọgọ́rùn-ún ó sì wà fún gbogbo ènìyàn láti ṣe àtúnṣe àti lò
Ṣii orisun
Orísun tó wà ní ìpadé
Ṣawari nodu ati awọn irinṣẹ iṣeto onibaara
Àwọn aṣayàn pọ loriṣirṣi lati ran o lọwọ pẹ̀lú iṣeto rẹ. Lo àwọn olutọka òkè yi fún iranlọwọ ilo àwon irinṣẹ isale wọnyi.
Awọn irinṣẹ nodu
Jọwọ ṣakiyesi pataki mimuonibaara kekerebi o ṣe n mu idagbasoke ba aabo ti nẹtiwọọki, ati adinku eewu rẹ. Awọn irinṣẹ ti o gba ọ laaye lati ṣeto onibara kekere ni a tumọ si "onibaara pupo."
Awọn Olupilese Kokoro
Awọn irinṣẹ wọnyi le ṣee lo bi asayan si CLI Ifipamo Idokowo(opens in a new tab) lati se iranwo pelu ipilese kokoro.
Ní àbá irinṣẹ idokowò tí a padanu? Boju wo àwọn ìlànà kikojọ ọja lati mo bi wọn ba dangajia, ki o ṣi fa won kale fún àtúnyẹ̀wò.
Explore home staking guides
Awon ibere gbogbo ìgbà
Iwọnyi jẹ diẹ ninu awọn ibeere ti o wọpọ julọ nipa idokowo ti o se pataki lati mo nipa.
Kíkà síwájú síi
- The Ethereum Staking Directory(opens in a new tab) - Eridian and Spacesider
- Ethereum's Client Diversity Problem(opens in a new tab) - @emmanuelawosika 2022
- Helping Client Diversity(opens in a new tab) - Jim McDonald 2022
- Client diversity on Ethereum's consensus layer(opens in a new tab) - jmcook.eth 2022
- How To: Shop For Ethereum Validator Hardware(opens in a new tab) - EthStaker 2022
- Step by Step: How to join the Ethereum 2.0 Testnet(opens in a new tab) - Butta
- Eth2 Slashing Prevention Tips(opens in a new tab) - Raul Jordan 2020