Ibùdó Ìdánwò kúkúrú
Ṣe ìdánwò ìmo Ethereum rẹ
Ṣàyẹ̀wò bí o ṣe lóye sí lórí Ethereum àti àwọn owó crypto. Ṣé o ti ṣe tán láti di ògbóǹtarìgì?
Àwọn ìpìlẹ̀ Ethereum
Abala yìí dá l'órí àwọn èrò ìpìlẹ̀ tí Ethereum, láti ríi dájú wípé o ní ìpìlè tó yè kooro.
- Kí ni Ethereum?5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Kíni ether (ETH)?4 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Àwọn wọ́lẹ́ẹ́tì4 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Kí ni Web3?5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Ààbò Ethereum àti ìdènà jìbìtì5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
Lílo Ethereum
Ṣàfikún ìmò rẹ nípa ohun ìlò Ethereum ní inú ayé kí o sì ri bí ìkànnì blockchain ṣe ń mú àtúntò bá ilé-iṣẹ́. Ọ̀nà tó dára nìyí láti ríi dájú wípé o lóye àwọn ǹkan dáadáa kí o tó bẹ̀rẹ̀ sí ní lo àwọn owó crypto.
- NFTs - Àwọn ààmì ohun tí a fi ń ṣe ọ̀ṣọ́5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Stablecoins5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- DeFi5 Àwọn ìbéèrèBEGINNER
- Ìpele 24 Àwọn ìbéèrèINTERMEDIATE
- DAOs5 Àwọn ìbéèrèINTERMEDIATE
- Mú nódù kan ṣiṣẹ́6 Àwọn ìbéèrèINTERMEDIATE
- The Merge5 Àwọn ìbéèrèINTERMEDIATE
- Mímú gbòòrò4 Àwọn ìbéèrèADVANCED
- Ìdókòwò aládaṣe7 Àwọn ìbéèrèADVANCED
Ṣé ẹ tún fẹ́ rí àwọn ìdánwò mìíràn si níbí?
Ṣàfikún sí ibi ìkówèésí wa.
Ṣàfikún ìbéèrè/ìdánwò
Apapọ àwọn àmì rẹ
0/69
Ìpíndọ́gba àmì: 0%Parí: 0/14
Ìsirò statistiki ti àwùjọ
- Ìpíndọ́gba àmì:67.4%
- Àwọn ìbéèrè tí a dáhùn:100,000+
- Iye ìgbà tí o gbìyànjú àtúnṣe:15.6%