Rékọjá sí àkóónú àkọ́kọ́
Àpèjúwe ìlú ọjọ́ iwájú kan, tó ń ṣojú àyíká Ethereum.

Káàbọ̀ sí Ethereum

Pẹpẹ asíwájú fún àwọn ohun èlò tuntun àti àwọn nẹ́tíwọọkì blockchain

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ lílò

Ọ̀nà tuntun láti lo íńtánẹ́ẹ̀tì

Crypto láìsí àìdánilójú

Stablecoins jẹ́ àwọn owó jẹ́ àwọn owó tó ní iye tó dúró ṣánṣán. Iye owó wọn bá dọ́là ilẹ̀ Amẹ́ríkà tàbí àwọn ohun ìní mìíràn tó dúró sán-ún mu.

Kọ́ ẹ̀kọ́ díẹ̀ síi

Ètò ìsúná àìsọ́júsàájú

Bílíọ́nù ènìyàn ni kò lè ṣí àkáǹtì ní báńkì tàbí kí wọ́n lo owó wọn ní ìrọ̀rùn. Ètò ìnáwó ti Ethereum ṣí sílẹ̀ nígbà gbogbo àti àìṣojúsàájú.

Ṣàwárí DeFi

Nẹ́tíwọọkì àwọn nẹ́tíwọọkì

Ethereum jẹ́ ibùdó fún ìsọdọtun blockchain. Àwọn iṣẹ́ tí ó dára jùlọ ni a gbé kalẹ̀ lórí Ethereum.

Ṣàwárí àwọn àǹfààní

Àwọn ohun èlò tuntun

Àwọn ohun èlò Ethereum ń ṣiṣẹ́ láìsí títa dátà rẹ. Dáàbò bo rẹ.

Ṣàwárí àwọn ohun èlò ẹ̀rọ

Íńtánẹ́ẹ̀tì ti àwọn ohun-ìní

Iṣẹ́ ọnà, ìwé ẹ̀rí tàbí dúkìá pàápàá ni a lè fi ṣe tọ́kẹ̀n. Ohunkóhun lè jẹ́ ohun ìṣòwò tọ́kẹ̀n. Ohun níni jẹ́ ti gbangba àti àrídájú.

Díẹ̀ si nípa NFTs

Iṣẹ́

Àyíká tó lágbára jù lọ

Iṣẹ́ láti gbogbo nẹ́tíwọọkì Ethereum

$148B
Iye tí a fi pamọ́ sínú DeFi
$125.7B
Iye tó ń dáàbò bo Ethereum
$0.25
Iye owó ìdúnàádúrà ìpíndọ́gba
19.87M
Àwọn ìdúnàádúrà ní àwọn wákàtí mẹ́rìnlélógún tó kọjá
Kọ́ ẹ̀kọ́

Lóye Ethereum

Crypto lè ka ni láyà. Má ṣàníyàn, àwọn ohun èlò yìí ni a ṣe láti ràn ọ́ lọ́wọ́ láti lóye Ethereum ní ìṣẹ́jú díẹ̀ péré.

Values

Íńtánẹ́ẹ̀tì ń yípadà

Jẹ́ ara ìyípadà dígítà

Ogún

Ethereum

Àwọn olùkọ́ ohun

Àwùjọ olùkọ́ ohun tó tóbi jù lọ ti Blockchain

Ethereum jẹ́ ilé sí àyíká olùdásílẹ̀ tó tóbi jù lọ àti tó ní agbára jù lọ ti Web3. Lo JavaScript àti Python, tàbí kí o kọ́ èdè àdéhùn ọlọ́gbọ́n bíi Solidity tàbí Vyper láti kọ ohun èlò tìrẹ.

Àpẹrẹ Kóódù

Àwùjọ Ethereum.org

Kíkọ́ nípasẹ̀ àwùjọ náà

Ojú òpó ethereum.org jẹ́ kíkọ́ àti ìṣètọ́jú nípasẹ̀ nípasẹ̀ ọgọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn atúmọ̀ èdè, àwọn olùpílẹ̀ṣẹ̀, àwọn oníṣẹ́ àrà, àwọn ònkọ̀wé, àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àwùjọ tó ní ìtara ní oṣoosù.

Wá bi àwọn ìbéèrè, sọpọ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé, kí o sì kópa nínú ìkànnì náà. Wàá ní ìrírí tó wúlò, wàá sì rí ìtọ́sọ́nà lákòókò ìlànà náà!

Àwùjọ Ethereum.org ni ibi tó dára jù láti bẹ̀rẹ̀ àti láti kọ́.

Àwọn àgbéjáde àìpẹ́

Àwọn àgbéjáde bulọọgi tuntun àti àwọn ìmúdójúìwọ̀n láti àwùjọ náà

Events

Àwọn àwùjọ Ethereum máa ń ṣètò àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ káàkiri àgbáyé, jálẹ̀ ọdún