Skip to main content

Kọ ẹkọ nipasẹ kiko koodu

Àwọn ohun èlò yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìdánwò pẹ̀lú Ethereum bí o bá fẹ́ ìrírí ẹ̀kọ́ tí ó ní ìbáraenisepọ̀.

Koodu sandbox

Àwọn sanndbox yìí yòó fún o ní ayẹ lati ṣe idanwo pèlú kikọ àwọn adehún ọlọgbọn ati mìmọ Ẹ́tẹ́ríọ́mù.

Àwòrán ìdánimọ̀ ChainIDE

ChainIDE

Béré Irinajo l'ori ẹ̀kọ́ Web3 nípa kíkọ́ adehun ologbon fun Ethereumu pèlú ChainIDE. Fi awon awose tí a ti pèsè s'ílẹ̀ lati ko ati dín àkòkó kù.
Solidity
web3
Ṣí ChainIDEopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Tenderly

Tenderly

Sandbox Tenderly je ayika àwòkọ́ṣe níbí tí o le tí ko, ṣe, ati wa ojutu àwọn adehún ọlọgbọn ní oju opo aṣàwákiri nipasẹ Solidity ati JavaScript.
Solidity
Vyper
web3
Ṣí Tenderlyopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Atlas

Atlas

Kọ, ṣe ìdánwò, àti ṣe àgbéjáde àdéhùn ọlọ́gbọ́n ní ìṣẹ́jú pẹ̀lú Atlas IDE.
Solidity
Ṣí Atlasopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Eth.build

Eth.build

Ohún ikẹ̀ẹ́kọ sandbox fún web3, pèlú ikosinú iseto wiwọ-ati-fifilẹ ati àwọn bulọọku orisun gbangba.
web3
Ṣí Eth.buildopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Remix

Remix

Ṣe idagbasoke, ṣe agbejade, ṣe akoso, adehún ọlọgbọn fún Ẹ́tẹ́ríọ́mù. Tẹ̀lé àwọn idanilẹkọ pèlú LearnEth plugin.
Solidity
Vyper
Ṣí Remixopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Replit

Replit

Ayika idagbasoke akanṣe kan fún Ẹ́tẹ́ríọ́mù pèlú isodotun, ayẹwọ aṣiṣe àti àtìleyin testnet to gaju.
Solidity
web3
Ṣí Replitopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Dapp World

DApp World

Ayika ilọsoke imo blockchain, to ni awọn iṣẹ-ekọ, awọn adanwo, igbaradi ta nfi ọwọ ṣe, ati awon idije lọsẹẹsẹ.
Solidity
web3
Ṣí DApp Worldopens in a new tab
Remix, Replit, ChainIDE, ati Atlas kìí ṣe sandbox lasán-- àwọn oniṣẹ ètò le ko, ṣe akojọpọ, ati ṣe agbejade àwọn adehún ọlọgbọn pèlú wọn.

Àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ eré ìdárayá alábàáṣepọ̀

Máa kẹ́kọ̀ọ́ bó o ṣe ń ṣeré. Àwọn ìdánilẹ́kọ̀ọ́ wọ̀nyí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti mọ àwọn ìpìlẹ̀ nípa lílo eré ìdárayá.

Àwòrán ìdánimọ̀ CryptoZombie

CryptoZombies

Gba ẹ̀kọ́ Solidity nípa kíkọ́ eré Zombie rẹ.
Solidity
Ṣí CryptoZombiesopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Ethernauts

Ethernauts

Parí awọn ipele nipaṣẹ akolu si adehun ologbon.
Solidity
Ṣí Ethernautsopens in a new tab
Gba àwòrán ìdánimọ̀ Ether

Capture The Ether

Capture the Ether ni ere ti a ma fi agbara wọle sinu adehun ọlọgbọn Ethereum lati kọ nipa aabọ.
Solidity
Ṣí Capture The Etheropens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Node Guardians

Node Guardians

Node Guardians jẹ pepe ikẹko oniṣeré tí àwọn oníṣẹ ètò web3 le lo lati kọ afilọlẹ Soliditiy, Cairo, ati Huff.
Solidity
web3
Ṣí Node Guardiansopens in a new tab

Ibudo ikẹko fun awọn olugbetokalẹ

Awọn isẹ ẹko tẹ ma sanwo fun to wa lori ayelujara lati gbe ẹ debi ti aye wa lọwọlọwọ, ni kiakia.

Àwòrán ìdánimọ̀ Platzi

Platzi

Kọ́ ẹ̀kọ́ bí o ṣe le kọ́ àwọn ohun èlò tí kò ní àkóso (Dapps) lórí Web3 àti kí o mọ̀ lámọ̀dájú gbogbo àwọn ìmọ̀ tí o nílò láti jẹ́ olùṣe ìdàgbàsókè blockchain.
Solidity
web3
Ṣí Platziopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Consensys Academy

ConsenSys Academy

Ibùdó ẹ̀kọ́ Olùgbéejáde Ethereum ti Orí ayélujára.
Solidity
web3
Ṣí ConsenSys Academyopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ BloomTech

BloomTech

Eto eko BloomTech Web3 ma ko é ni nkan ti awon Agbani si ise n'ilo n'inu awon onimo ero.
Solidity
web3
Ṣí BloomTechopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Questbook

Questbook

Ikekọ́ ní àkọ́kọ̀ ara ẹni láti kọ́ kíkọ́ Web 3
Solidity
web3
Ṣí Questbookopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ _metaschool

Metaschool

Dí oníṣẹ ètò web3 nipasẹ ṣiṣẹda ati fífíranṣẹ àwọn dApp.
Solidity
web3
Ṣí Metaschoolopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ NFT school

NFT School

Ṣawarí ńkan tí o n lọ lori token alailẹgbẹ, tabi àwọn NFT lati apa ikọṣẹmọṣẹ.
Solidity
web3
Ṣí NFT Schoolopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Speed Run Ethereum

Speed Run Ethereum

Ẹ́tẹ́ríọ́mù Speed Run jẹ akojọpọ idojukọ lati ṣayẹwo ìmọ̀ rẹ̀ lori Solidity pèlú lilo Scafffold-ETH
Solidity
web3
Ṣí Speed Run Ethereumopens in a new tab
Àwòrán ìdánimọ̀ Alchemy University

Alchemy University

Ṣe idagbasoke iṣẹ́ web3 rẹ nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ ìkẹ̀kọ́, àwọn iṣẹ́ àkànṣe àti kóòdù.
Solidity
web3
Ṣí Alchemy Universityopens in a new tab
LearnWeb3 logo

LearnWeb3

LearnWeb3 is a free, high quality education platform to go from zero to hero in web3 development.
Solidity
web3
Ṣí LearnWeb3opens in a new tab
Cyfrin Updraft logo

Cyfrin Updraft

Learn smart contract development for all skill levels and security audits.
Solidity
web3
Ṣí Cyfrin Updraftopens in a new tab

Ǹjẹ́ ojú-ìwé yìí ṣe ìrànlọ́wó?