Rékọjá sí àkóónú àkọ́kọ́

Bí o ṣe lè fi ETH rẹ̀ dókòwò

Jèrè látara dídáàbò bò Ethereum

Èyíkéyìí olùṣàmúlò pèlú iye ETH kankan lè ṣèrànwọ́ láti dáàbò bò nẹ́tíwọọkì náà, èrè sì wà nípasẹ̀ rẹ̀.

Àwòrán maskooti eranko ìmọ̀dò fún páádì ìfilọ́lẹ̀ ìdókòwò.
34,215,444
Àpapọ̀ ETH tí a ti fi dókòwò
1,068,268
Àpapọ̀àwọn olùṣàyẹ̀wò
3.5%
APR tó wà lọ́wọ́lọ́wọ́

Kí ni ìdókòwò?

Dídókòwò jẹ́ iṣẹ́ tí ìwọ bá fi ETH méjìlélọ́gbọ̀n sílẹ̀ láti mú sofitiwia ṣiṣẹ́. Gẹ́gẹ́ bíi olùṣàyẹ̀wò, ìwọ yóò ní ojúṣe fún àfipamọ́ dátà, ṣíṣètò àwọn ìdúnàádúrà, àti fífi tuntun sóri blockchain náà. Èyí yóò mú Ethereum wà ní ààbò fún gbogbo ènìyàn, ìwọ yóò jèrè ETH tuntun nínú ìlànà náà.

Ìdí dídókòwò ETH rẹ?

Jèrè

Èrè wà fún àwọn iṣẹ́ tó ṣe ìrànlọ́wọ́ fún nẹ́tìwọ́ọ̀kì láti dé . Ìwọ yóò gba ẹ̀rè fún mímú sọfitiwia ṣiṣẹ́ tó ń ṣètò àwọn ìdúnàádúrà sí àwọn búlọ́ọ́kù tuntun tí ó bá àwọn ìṣòwò pọ̀ sí àwọn bulọọki tuntun àti ṣayẹwo iṣẹ́ àwọn oluṣàyẹ̀wò mìíràn nítorí pé èyí ni ó ń jẹ́ kí ẹ̀dá náà le ṣiṣẹ́ ní ààbò.

Ààbò tó dára jùlọ

Nẹtiwọọkí yóò ní agbára sí ìkọlù bíi ídokòwò ETH bá ṣe pọ̀ sí, ó sì nílò ETH pupọ sí làti ṣàkóso púpò nínú nẹ́tíwọọkì náà. Làti jẹ́ ìhàlẹ̀, ọ nílò láti ní àkóso ọ̀pọ̀ nínú àwọn olùfọwọ́sí, eyí túmọ̀ sí pé o nílò láti darí ọ̀pọ̀ ETH tó wà nínú ẹ̀rọ náà - ìyẹn pọ̀ gan-an!

Ní ìmúdúró síi

Àwọn olùdókòwò kò nílò láti ṣe àwọn ìṣirò ẹ̀rí iṣẹ́-ṣíṣe alagbára púpọ̀ láti kópa nínú ìdáàbòbò nẹ́tíwọọkì náà èyí túmọ̀ sí pé àwọn nódù ìdókòwò lè ṣiṣẹ́ lórí ẹrọ oní ìwọ̀nba, nípasẹ̀ lílo agbára kékèké.

Àwọn àlàyé díẹ̀ síi nípa agbára lílò Ethereum

Bí o ṣe lè fi ETH rẹ̀ dókòwò

Ó dá lórí iye owó tí o fẹ́ fí dókòwò. Wàá nílò ETH méjìlélọ́gbọ̀n láti mú olùṣàyẹ̀wò rẹ ṣiṣẹ́, ṣùgbọ́n ó ṣeé ṣe láti fi owó díẹ̀ dókòwò.

Wo àwọn àṣàyàn tó wà ní isalẹ kí o sì yàn ẹ̀yà tó dára jùlọ fún ìwọ àti fún nẹ́tìwọ́ki náà.

Home staking

Tó ní ipa tó pọ̀ jùlọ

Ìṣàkóso lẹ́kunrẹ́rẹ́

Èrè kíkún

Àìní ìgbẹ́kẹ̀lé

Home staking on Ethereum is the gold standard for staking. It provides full participation rewards, improves the decentralization of the network, and never requires trusting anyone else with your funds.

Those considering staking from home should have some amount of ETH and a dedicated computer connected to the internet ~24/7. Some technical know-how is helpful, but easy-to-use tools now exist to help simplify this process.

Home stakers can pool their funds with others, or go solo with at least 32 ETH. Liquid staking token solutions can be used to maintain access to DeFi.

More on home staking

Ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́ kan

ETH méjìlélọ́gbọ̀n rẹ

Àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé àṣírí olùṣàyẹ̀wò rẹ

Nódù ìṣiṣẹ́ alágbẹ́kẹ̀lé

Tí o kò bá fẹ́ tàbí níní nǹkan ṣe pẹ̀lú kọ̀ǹpútà kò rọrùn fún ọ ṣùgbọ́n o ṣì fẹ́ láti ṣe ìdókòwò ETH méjìlélọ́gbọ̀n rẹ, àṣàyàn ìdókòwò-gẹ́gẹ́-bíi-ìṣẹ́ le jẹ́ kí o fi apá tó nira sílẹ̀ fún ẹlòmíràn, nígbà tí o bá ń ri tí ìwọ yóò sì máa jẹ èrè búlọ́ọ́kù abínibí.

Àwọn àṣàyàn yìí máa ń kọ́ iwọ nípa bí a ṣe lè ṣẹ̀dá àwọn èlò olùyẹ̀wò, kí o ba lè fi àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlẹ́ rẹ̀ ránṣẹ́ sí wọn, àti kí o fi ETH méjìlélọ́gbọ̀n rẹ sílẹ̀. Èyí yòó jẹ́ kí alákóso iṣé ṣàyẹ̀wò dípò rẹ.

Ìru ìlànà ídokòwò yìí nílò irú ìpele ìgbọ́kànlé kan nínú olùpèsè ìṣẹ́ náà. Láti dín ewu alákóso kù, àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé láti fi yọ ETH rẹ wà ní ìṣàkóso rẹ.

Ìdókòwò alápapọ̀

Ṣe ìdókòwò pẹ̀lú iyekíye

Jèrè

Ṣeé ní ṣókí

Gbajúgbajà

Several pooling solutions exist to assist users who do not have or feel comfortable staking 32 ETH.

Ọ̀pọ̀ nínú àwọn àṣàyàn wọ̀nyí ni a mọ̀ sí ‘liquid staking’ tó ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú tọ́kẹ̀n alásọdowó tó jẹ́ aṣojú ETH tí o fi dókòwò.

Liquid staking makes staking and unstaking as simple as a token swap and enables the use of staked capital in DeFi. This option also allows users to hold custody of their assets in their own Ethereum .

Ìdókòwò aládàpọ̀ kò jẹ́ ti abínibí nẹ́tíwọọkì Ethereum. Àwọn alákóso ẹnì kẹta ni ó dá àwọn ọ̀nà ojútùú wọ̀nyí, wọ́n sì fi orí ti àwọn ewu tó rọ̀ mọ.

Àwọn pàsípáàrọ̀ alákóso

Tó ní ipa tó kéré jù lọ

Àwọn àbá ìgbẹ́kẹ̀lé tí ó ga jùlọ

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìṣàkóso pàṣípààrọ̀ ń pèsè iṣẹ́ ìdókòwò tí kò bá tíì rọ́run fún ọ pẹ̀lú fífi ETH sílẹ̀ nínú wọ́lẹ́ẹ́tì tìrẹ. Wọ́n lè jẹ́ aṣayan tó jẹ́ kí o lè rí èrè diẹ̀ lórí ìṣàkóso ETH rẹ̀ pẹ̀lú iṣẹ́ kékeré.

Ìjuwọ́sílẹ̀ ibẹ̀ ni pé àwọn olùpèsè aláìlákóso ṣàkójọpọ̀ ETH ńlá láti mú àwọn oluṣàyẹ̀wò púpọ̀ ṣiṣẹ́. Èyí lè jẹ́ ewu fún nẹ́tíwọọkì náà àti àwọn olùsamulo rẹ̀ nítorí ó ṣe ìdásílẹ̀ ìdojúkọ alákóso ńlá àtí ọ̀nà ìkùnà, tí yóò mú kí olùpèsè náà súnmọ́ ìkọlù tàbí ìpalára.

Tí kò bá tẹ́ ẹ lọ́run láti wà pẹ̀lú rẹ, ó dára. Àwọn àṣàyàn yìí wà fún ọ. Ní àkókò yìí, ro láti wo ojú-ìwé wọ́lẹ́ẹ́tì wa, níbi tí o ti lè bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ nípa bí o ṣe lè ní ìṣàkóso gidi lórí owó rẹ. Nígbà tí o bá ṣetán, padà wá kí o sì gbèrú eré ìdókòwò rẹ nípa fí fúnra gbígbìyànjú ara àwọn iṣẹ́ ìdókòwò alápapọ̀ tó wà ní ìpèsè.

Bí o sì ti le ṣàkíyèsí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà lo wà láti kópa nínú ìdokòwò Ethereum. Àwọn ọ̀nà wọ̀nyí ń fojúsun ọ̀pọ̀ àwọn olùṣàmúlò, àti pé ìkọ̀ọ̀kan wọn yàtọ̀ nípa àwọn ewu, èrè, àti àbá ìgbẹ́kẹ̀lé. Àwọn mìíràn jẹ́ aláìlákóso díẹ̀ síi, tí wọ́n yege àyẹ̀wò àti/ó sì lèwù diẹ̀ ju àwọn mìíràn lọ. A pèsè àwọn àlàyé nípa àwọn ìṣẹ́ àkànṣe tó gbajumọ̀ nínú àgbègbè yìí, ṣùgbọ́n ri dájú pé o ṣe ìwádìí tìrẹ ṣáájú kí o tó fi ETH sí ibikíbi.

Àfiwé àwọn àṣàyàn ìdókòwò

Kò sí ojútù kan pato fún gbogbo ènìyàn nínú idokowò, àti pe ojútù kòókan yatò́. Níhìn, a máa ṣe afiwe àwọn ewu, èrè, àti àwọn ńkan ti a nilo tó wà nínú àwọn ọ̀nà oríṣiríṣi tí o lè fi dokowò.

Home staking

Àwọn Èrè

  • Iye èrè tó ga jù - gba gbogbo èrè tààrà láti orí ìlànà náà
  • Rewards for proposing blocks, including unburnt transaction fees, and attesting regularly to the state of the network
  • Option to mint a liquid staking token against your home node to be used in DeFi

Àwọn ewu

  • ETH rẹ wà nínú ewu
  • Àwọn ìbáwí wà, tó jẹ́ pẹ̀lú ETH, fún kí kúrò lórí ayélujára
  • Slashing (larger penalties and ejection from the network) for malicious behaviour
  • Minting a liquid staking token will introduce smart contract risk, but this is entirely optional

Àwọn ìnílò

More on home staking

Ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́ kan

Àwọn Èrè

  • Nígbà gbogbo ó pẹ̀lú àwọn èrè ìlànà ní kíkún pẹ̀lú ìyọkùrò owó oṣooṣù fún àwọn iṣẹ́ nódù
  • Àwọn dáṣíbọ́ọ̀dù sábà máa ń wà láti jẹ́ kí ó rọrùn láti tọpasẹ̀ oníbàárà olùṣàyẹ̀wò rẹ

Àwọn ewu

  • Ewu kan náà bíi ìdókòwò aládaṣe pèlú àfikún ewu ìdojúkọ ẹgbẹ́ ti olùpèsè iṣẹ́
  • Lílo àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwolẹ́ rẹ ni o fi sí ọwọ́ ẹlòmíràn tó lè hùwà àìṣedéédéé

Àwọn ìnílò

  • Fi ETH méjìlélógbọ̀n sílẹ̀ wàà sí ṣẹ̀dá àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé àṣírí rẹ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́
  • Tọ́jú àwọn ọ̀rọ̀ ìgabaniwolé àṣírí dáadáa
  • Àwọn tó kù ni a ti bójútó, ṣùgbọ́n àwọn iṣẹ́ pàtàkì yóò yàtọ̀ sí ara wọn
Àlàyé síi nípa ìdókòwò gẹ́gẹ́ bíi iṣẹ́

Ìdókòwò alápapọ̀

Àwọn Èrè

  • Àwọn onídókòwò àpapọ̀ máa ń gba èrè ní ọ̀nà tó yàtọ̀, ó dá lórí irú ọ̀nà ìdókòwò àpapọ̀ tí wọ́n yàn
  • Ọ̀pọ̀ iṣẹ́ ídòkowò alápapọ̀ máa ń pèsè ọ̀kan tàbí díẹ̀ síi èyí tó sójú ETH tí o fi dókòwò pẹ̀lú ìpín rẹ̀ nínú èrè àwọn olùṣàyẹ̀wò
  • Àwọn tọ́kẹ̀n ìsọdowó lè wà nínú wọ́lẹ́ẹ́tì rẹ, tàbí kí o lò wọn ní o sì lè tà wọ́n tí o bá pinnu láti jáde kúrò

Àwọn ewu

  • Àwọn ewu dá lórí irú ìlanà tí a lò
  • Ní àkótán, àwọn ewu jẹ́ àpapọ̀ ìdojúkọ ẹgbẹ́ àti ewu ìmúlò

Àwọn ìnílò

  • Awọn ìbéèrè ETH tó kéré jù lọ, àwọn iṣẹ́ kan nílò bíi 0.01ETH
  • Fi owó ní tààrà láti inú wọ́lẹ́ẹ́tí rẹ sínú àwọn oríṣiríṣi pẹpẹ ídókòwò alápapọ̀ tàbí ra ọ̀kan nínú àwọn tọ́kẹ̀n ìsọdowó ti dídókòwò
Díẹ̀ síi nípa ìdókòwò alápapò

Àwọn Ìbéèrè Gbogbo ìgbà

Ǹjẹ́ ojú-ìwé yìí ṣe ìrànlọ́wó?