Rékọjá sí àkóónú àkọ́kọ́

Stablecoins

Owó dígítà fún lílo ojoojúmọ́

Stablecoins jẹ́ àwọn tọ́kẹ̀n Ethereum tí a ṣe láti dúró ní iye tó wà títí, pàápàá nígbàtí ìdíyelé ti ETH bá yípadà.

Àwọn stablecoins mẹ́ta tó tóbi jù lọ nípasẹ̀ iye ọjà: Dai, USDC, àti Tether.

Kí nìdí tó fi jẹ́ stablecoins?

Stablecoins jẹ́ àwọn owó crypto tí kò ní àyípadà. Wọ́n ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbára kan náà bíi ETH ṣùgbọ́n iye wọn jẹ́ ìdúróṣinṣin díẹ̀ síi bíi owó ìbílẹ̀. Nítorí náà o ní ààyè sí owó tí ó dúró sán-ún tí o lè lò lórí Ethereum. Bí àwọn stablecoin ṣe gba ìdúróṣinṣin wọn

Stablecoins jé nǹkan tó káàkiri àgbáyé, ọ sì lè fi ránṣẹ́ lórí ayélujára. Ọ rọrùn láti gbà tàbí fi ránṣẹ́ tí ọ bá ní .

Ìbéèrè fún stablecoins ga, nítorí náà o lè rí èlé gbà tí o bá yá ni a lówó rẹ. Ríi dájú pé o mọ àwọn ewu tó wà níbẹ̀ kó o tó yá ni lówó.

Wón lè fí stablecoins pààrọ̀ ETH àti àwọn tọ́kẹ̀n Ethereum. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ gbára lé stablecoins.

Stablecoins ní àabò tó péye pẹ̀lú . Kòsí ẹnikẹ́ni tó lè fi owó ránṣẹ́ léyìn rè.

Pizza Bitcoin tó gbajúmọ̀

Ní ọdún 2010, ẹnìkan ra pizzà méjì fún 10,000 bitcoin. Ní àkókò ti àwọn wọ̀nyí ní ó tó ~ $ 41 USD. Ní ọjà òde òní, èyí tó àwọn mílíọ̀nù dọ́là. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú àwọn ìdúnàádúrà tí a kábàámọ̀ fún ló wà nínú ìtàn Ethereum. Àwọn stablecoin yanjú ìṣòro yìí, nítorí náà o lè gbádùn pizza rẹ kó o sì di ETH rẹ mú.

Wa stablecoin kan

Ọgọgọ́ọ́rún stablecoins ló wà lárọ̀ọ́wọ́tó. Èyí ni díè nínú wọn láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ láti bẹ̀rẹ̀. Bí o bá jẹ́ ẹni tuntun sí Ethereum, a dábàá pé kí o ṣe ìwádìí díẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́.

Àwọn àṣàyàn àwọn olóòtú

Ìwọ̀nyí jẹ́ àwọn àpẹẹrẹ tí a mọ̀ jùlọ ti àwọn stablecoins ní báyìí àti àwọn owó tí a ti rí ìwúlò wọn nígbà tí a bá ń lo dapps.

Dai

Dai ni ó ṣeé ṣe kí ó jẹ́ olókìkí stablecoin aláìlákóso jù lọ. Iye rẹ jẹ́ bíi dọ́là kan àti pé wọ́n gbà á káàkiri dapps.

Pààrọ̀ ETH fún Dai(opens in a new tab)
Kọ́ ẹ̀kọ́ nípa Dai(opens in a new tab)
Àmì-ìdánimọ̀ Dai náà

USDC

USDC ni ó ṣeé ṣe ni stablecoin olókìkí jùlọ tó ní àtìlẹyìn owó bébà. Iye rẹ jẹ́ bíi dọ́là kan àti pé o ní àtìlẹyìn nípasẹ̀ Circle àti Coinbase.

Ààmì ìdánimọ̀ USDC náà

Àwọn stablecoin tó ga jùlọ nípasẹ̀ gbogbo owó ọjà

Àwọn stablecoin alugorítìmí ni ìmọ̀-ẹ̀rọ ìdánwò. Ó yẹ kí o mọ àwọn ewu ṣáájú lílo wọn.

Gbogbo owó ọjà ni iye ti gbogbo awọn tọ́kẹ̀n tó wà ní ìlọ́po nípasẹ̀ iye fún tọ́kẹ̀n kan. Àtòjọ yìí jẹ àyípadà àti àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí a ṣe àtòjọ níbí kò ní láti jẹ́ èyí tí ẹgbẹ́ ethereum.org fọwọ́ sí.

OwóGbogbo owó ọjàIrú ohun ìṣèdúró
Tether
$138,253,710,469Owó bébàLọ si Tether(opens in a new tab)
USDC
$41,113,264,903Owó bébàLọ si USDC(opens in a new tab)
Dai
$3,491,975,555CryptoLọ si Dai(opens in a new tab)

Bí o ṣe lè gba stablecoins

Ṣe àfipamọ́ pẹ̀lú stablecoins

Àwọn stablecoin máa ń ní iye owó èlé tó ga ju àpapọ̀ lọ nítorí ìbéèrè púpọ̀ wà fún yíyá wọn. Àwọn dapps wà tó jẹ́ kí o lè gba èlé lórí àwọn stablecoins rẹ ní àkókò gidi nípa fífi wọn sínú àgbá tó ń yáwó. Gẹ́gẹ́ bíi àgbáyé ilé-ìfowópamọ́, o ń pèsè àwọn tọ́kẹ̀n fún àwọn olùyáwó ṣùgbọ́n o lè yọ àwọn tọ́kẹ̀n rẹ kúrò àti èlé rẹ nígbàkigbà.

Awọn dapps tó ń jèrè

Lo owó ìpamọ́ stablecoin dáadáa, kó o sì rí èlé gbà. Bíi ti ohun gbogbo tó wà nínú crypto, Àwọn ìkórè Ọdọọdún ti àsọtẹ́lẹ̀ (APY) lè yí padà láti ọjọ́ kan sí òmíràn tó dá lórí ìpèsè/ìbéèrè ní àkókò gidi.

0.05%

Ìpíndọ́gba owó tí àwọn báńkì ń san lórí àwọn àkántì ìpìlẹ̀ ìpamọ́ tí ìjọba àpapọ̀ fi ààbò bo ti Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Orísun(opens in a new tab)
Ààmì ìdánimọ̀ Ave

Aave(opens in a new tab)

Àwọn ọjà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ stablecoins, pẹ̀lú Dai, USDC, TUSD, USDT, àti síwájú síi.

Ààmì ìdánimọ̀ Compound

Compound(opens in a new tab)

Yá ni ní stablecoins kí o si gba èlé àti $COMP, tọ́kẹ̀n ti Compound.

Ààmì ìdánimọ̀ Summer.fi

Summer.fi(opens in a new tab)

Ohun èlò kan tí wọ́n ṣe láti fi ṣe àfipamọ́ Dai.

Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́: oríṣi stablecoin

Ṣe ìwádìí ti ara rẹ nígbà gbogbo

Àwọn stablecoin alugorítìmí ni ìmọ̀-ẹ̀rọ ìdánwò. Ó yẹ kí o mọ àwọn ewu ṣáájú lílo wọn.

Tó ní àtìlẹyìn fiat

Ní pàtàkì IOU (Mo jẹ ọ́ ní gbèsè) fún owó bébà (nígbà gbogbo dọ́là). O lo owó bébà rẹ láti ra stablecoin tí o lè fi ra owó tó bá yá àti fi ṣe ìràpadà owó dígítà rẹ.

Pros

  • Ààbò lọ́wọ́ àìdánilójú owó crypto.
  • Ìyípadà nínú iye owó kò tó nǹkan.

Cons

  • Tó ní àkóso - ẹnìkan gbọdọ̀ fúnni ní àwọn tọ́kẹ̀n náà.
  • Ó nílò àyẹ̀wò láti ríi dájú pé ilé-iṣẹ́ ní àwọn ifìṣúra tó tó.

Example projects

  • USDC(opens in a new tab)
  • TrueUSD(opens in a new tab)

Àtìlẹyìn crypto

Àwọn irin iyebíye

Alugọ́rídíìmù

Kọ́ ẹ̀kọ́ díẹ̀ síi nípa stablecoins

Dáṣíbọ́ọ̀dù àti Ẹ̀kọ́

  • Stablecoins.wtf
    Stablecoins.wtf
    Stablecoins.wtf ń fúnni ní dáṣíbọ́ọ̀dù pẹ̀lú àwọn dátà ìtàn ọjà, àwọn ìṣirò, àti àkóónú ẹ̀kọ́ fún àwọn stablecoins olókìkí jùlọ.
    Lọto Stablecoins.wtf website(opens in a new tab)

Ṣe ìdánwò ìmo Ethereum rẹ

Ǹjẹ́ ojú-ìwé yìí ṣe ìrànlọ́wó?